HYMN 60

6.7s (FE 77)
Tune: “Apata Ayeraiye"1. AWA Egbe Kerubu

  Ati Serafu laiye

  Awa mbebe fun ‘ranwo

  Agbara Emi Mimo.

Egbe: A! Baba sanu fun wa

      ko dari ese ji wa.


2. Ki fitila Re ma ku

   Ninu Eghe Serafu

   Ki gbogbo isesi wa

   Fi wa han bi Omo Re.

Egbe: A! Baba sanu fun wa

      ko dari ese ji wa.


3. Mase ta wa nu kuro

   Iwo olugbala wa

   K‘awa ma ba sako Io,

   Mu wa rIn ona tire.

Egbe: A! Baba sanu fun wa

      ko dari ese ji wa.


4. Jehovah Jire Baba,

   Pese f'awon alaini

   At’awon ti ko ri se

   Masai ranti won loni.

Egbe: A! Baba sanu fun wa

      ko dari ese ji wa.


5. Ese wa ti papo ju,

   Bi yanrin eti okun

   Awa nfe ‘mularada

   lwenumo ese wa.

Egbe: A! Baba sanu fun wa

      ko dari ese ji wa.


6. Jehovah Emmanueli,

   Iwo ni ireti wa,

   Mase je koju ti wa

   L'ojo nla 'dajo.

Egbe: A! Baba sanu fun wa

      ko dari ese ji wa.


7. Odagutan Olorun

   Baba at’Emi Mimo

   We ma mo patapata,

   Ko to kuro laiye yi.

Egbe: A! Baba sanu fun wa

      ko dari ese ji wa. Amin

English »

Update Hymn