HYMN 601

C.M. 388 H.C. 179 11 10s (FE 627)
"Wasu ihinrere fun gbogbo eda"
- Mark. 16:151. YO awon ti nsegbe

   Sajo eni nku

   F‘anu ja awon kuro ninu ese,

   Ke f'awon ti nsina, gb‘eni subu ro,
 
   So fun won pe, Jesu le gba won la.

Egbe: Yo awon ti nsegbe

      Sajo eni nku lo

      Alanu ni Jesu, yio gbala.


2. Bi nwon o tile, gan

   Sibe, O nduro

   Lati gb‘omo t‘o ronupiwada

   Sa f ‘itara ro won, si ro won jeje

   On o dariji, bi nwon je gbagbo.

Egbe: Yo awon ti nsegbe...


3. Yo awon ti nsegbe Ise tire ni

   Oluwa yio f‘agbara fun O

   Fi suru ro won pada s’ona toro

   So f’asako p’Olugbala ti ku lo.

Egbe: Yo awon ti nsegbe

      Sajo eni nku lo

      Alanu ni Jesu, yio gbala. Amin

English »

Update Hymn