HYMN 603

(FE 629)
“Oluwa awon omo-ogun, ibukun ni
fun eni no ti ogbekle O" - Ps. 84:12
Tune: Ikore aiye fere gbo1. E DIDE omo igbala

   To romo Olori wa

   E dide orile ede

   Ki ota to de Sion.

Egbe: E ko orin, to dun pupo

      E korin to dun pupo

      Bi hiho omi okun

      Nipa eje Olugbala

      Awa ju asegun Io- asegun lo

      Awa ju asegun lo- asegun.


2. E wa bu omi igbala

   Enyin omo araiye

   E wa gba igbala lofe

   T’Oluwa pese fun wa.

Egbe: E ko orin, to dun pupo...


3. Jesu f'ogoj’odun bebe

   Fun Egbe Serafu yi

   Lati fi ra aiye pada

   Ninu ese wa gbogbo.

Egbe: E ko orin, to dun pupo...


4. Ogo ni fun Baba, Omo

   Emi Mimo lo de yi
  
   Jowo fo gbogbo wa mo lau

   Nini ese wa gbogbo.

Egbe: E ko orin, to dun pupo

      E korin to dun pupo

      Bi hiho omi okun

      Nipa eje Olugbala

      Awa ju asegun Io- asegun lo

      Awa ju asegun lo- asegun. Amin

English »

Update Hymn