HYMN 610

t.H.C 366 8s.7s. (FE 636)
"Ko lati se rere" - Isa.1:7 
Tune: Oluwa da agan lohun1. WA nigbati Kristi npe o 

   Wa, ma rin‘nu ese mo

   Wa tu gbogb’ ohun to de o 

   Wa bere 're je t’orun.

Egbe: O npe, o nisiyi)

     Gbo b‘Olugbala ti npe) - 2ce


2. Wa nigbati Kristi mbebe 

   Wa gbo ohun ife Re

   Wo o ko ohun ife Re 

   Wo o si ma sako sa.

Egbe: O npe, o nisiyi...


3. Wa, mase f’akoko d’ola 
 
   Wa, ojo 'gbala niyi

   Wa fi ara re fun Kristi 

   Wa wole niwaju Re.

Egbe: O npe, o nisiyi

     Gbo b‘Olugbala ti npe

     O npe, o nisiyi

     Gbo b‘Olugbala ti npe. Amin

English »

Update Hymn