HYMN 611

P.M (FE 637)1. WA sodo Jesu, mase duro 

   L’oro Re l’O ti f’ona han wa 

   O duro li arin wa loni

   O nwi jeje pe ‘Wa.

Egbe: Ipade wa yio je ayo

     Gb’okan wa ba bo Iowo ese

     T’a o si wa pelu Re Jesu 

     Ni ile wa lailai.


2. Jek’ omode wa, A gbohun Re

   Jek’okan gbogbo ho fun ayo

   Ki a si yan On l’ayanfe wa

   Ma duro sugbon wa.

Egbe: Ipade wa yio je ayo...


3. Tun ro o wa pelu wa loni 
 
   F’eti s’ofin Re, k’o si gbagbo 

   Gbo b’ohun Re ti nwi pele, pe 

   Enyin omo mi wa.

Egbe: Ipade wa yio je ayo

     Gb’okan wa ba bo Iowo ese

     T’a o si wa pelu Re Jesu 

     Ni ile wa lailai. Amin

English »

Update Hymn