HYMN 613

O.t.H.C 245 S.M (FE 639) 
“Kini iwo si duro si nisisiyi? dide 
ki a baptist re, ki iwo ki o si we 
ese re nu, ki o si mape oruko 
Oluwa" - Ise.22:161. DURO, omo ogun 

   F’enu re so f’aiye

   Si jeje pe o ofo l’aiye 

   Nitori Jesu re.


2. Dide k’a baptis’ re

   K’a we ese re nu

   Wa b‘Olorun da majemu 

   So ‘gbagbo re loni.


3. Tire ni Oluwa

   At’ijoba orun

   Saa gb’ami yi siwaju re 

   Ami Oluwa re.


4. Wo k’ise t’ara re 

   Bikose ti Kristi

   A ko oruko re po mo 

   Awon mimo gbani.


5. Ni hamora Jesu

   Kojuja si Esu

   B’o ti wu k’ogun na le to 

   Iwo ni o segun.


6. Ade didara ni

   Orin na, didun ni

   Gbat t‘a ba ko ikogun jo, 

   S’ese Olugbala. Amin

English »

Update Hymn