HYMN 62

(FE 79)1. OLUWA mi, mo nkepe O,

   Ngo ku b‘O ko ran mi Iowo

   Jo fi igbala Re fun mi,

   Gba mi bi mo ti ri.

Egbe: Gba mi bi mo ti ri (2ce)

      Kristi ku fun mi l'ebe mi,

      Gba mi bi mo ti ri.


2. Emi kun fun ese pupo

   O ta ‘je Re le fun mi

   O le se mi bi O ba tl fe

   Gba mi bi mo ti ri.

Egbe: Gba mi bi mo ti ri...


3. Ko si ‘le ti mo le pamo

   Ngo ko le duro ti ‘pinnu mi,

   Sibe ‘tori Tire gba mi,

   Gba ale gbat‘orun wo.

Egbe: Gba mi bi mo ti ri...


4. Wo mi! mo wole l‘ese Re,

   Se mi bi o ba ti to si

   Bere ‘se Re, si pari re

   Gba mi bi mo ti ri.

Egbe: Gba mi bi mo ti ri... Amin

English »

Update Hymn