HYMN 620

C.M.S 454 H.C 2nd Ed 329 t. S. 
668. S.M (FE 646)
"Enikeni ti o gba okan ninu awon 
omode wonyi li oruko Mi, o gba 
mi" - Marku 9:371. EMI Olorun wa,

   Baptis awon wonyi

   Ba won da majemu mimo 

   We won kuro l'ese.


2. F’opa esu tutu

   We won n'nu eje Re 

   Baba, Omo, Emi Mimo

   So nwon di Omo Re. Amin

English »

Update Hymn