HYMN 623

C.M.S 500 H.C 449 2nd Ed t.S.65 
P.M (FE 649)
"Okan mi ti mura, Olorun, okan 
mi ti mura" - Ps. 57:71. OJO nla l’ojo ti mo yan 

   Olugbala l‘olorun mi

   O ye ki okan mi ma yo 

   Ko si ihin na kale.

Egbe: Ojo nla I’ojo na!

      Ti Jesu we ese mi nu

      O ko mi ki nma gbadura 

      Ki nma sora, ki nsi ma yo 

     Ojo nla I'ojo na! 

     Ti Jesu we ese mi nu.


2. Ise igbala pari na

   Mo di t’Oluwa mi loni 

   On l'o pe mi ti mo si je 

   Mo f’ayo j’ipe mimo na 

Egbe: Ojo nla I’ojo na...


3. Eje mimo yi ni mo je 

   F‘Eni to ye lati feran 

   Jek’orin didun kun ‘le Re 

   Nigba mo ba nlo sin nibe.

Egbe: Ojo nla I’ojo na...


4. Simi aiduro okan mi 

   Simi le Jesu Oluwa 

   Tani je wipe aiye dun 

   Ju odo awon Angeli. 

Egbe: Ojo nla I’ojo na...


5. Enyin orun, gbo eje mi 

   Eje mi ni ojojumo 

   Em‘o ma so d’otun titi 

   lku y‘o fi mu mi re le.

Egbe: Ojo nla I’ojo na!

      Ti Jesu we ese mi nu

      O ko mi ki nma gbadura 

      Ki nma sora, ki nsi ma yo 

     Ojo nla I'ojo na! 

     Ti Jesu we ese mi nu. Amen

English »

Update Hymn