HYMN 634

C.M.S 501, H.C 521 C.M (FE 660) 
“Emi nlepa Iati de ibi ami ni fun 
ere ipe giga Olorun" - Filip. 3:141. JI, okan mi, dide giri 

   Ma lepa nso kikan 

   F'itara sure ije yi 

   Fun ade ti ki sa.


2. Awosanma eleri wa 

   Ti nwon nf’oju sun o 

   Gbagbe irin atehinwa 

   Sa ma te siwaju.


3. Olorun nf’ ohun igbera 

   Ke si o lat’oke 

   Tikare l’O npin ere na

   T'o nnoga lati wo.


4. Olugbala Wo l'o nmu mi 

   Bere ije mi yi

   Nigbat’ ba de mi l'ade

   Ngo wole lese Re. Amin

English »

Update Hymn