HYMN 644

(FE 670) 
"Nwon o si je temi ni ini kan."1. MO ti ni Jesu l‘ore,

   Yebiye l’o je fun mi

   On nikan l’arewa ti okan mi fe 

   On ni itanna ipado,

   Ninu re ni mo rti

   lwenumo ati imularada 

   Olutunu, mi l’o je

   Ninu gbogbo wahala

   On ni ki nko eru mi l’on lori. 

Egbe: On ni ltanna ipada

      Irawo Owuro

      On nikan l'arewa ti okan mi fe 

      Olutunu mi l’o je

      Ninu gbogbo wahala

      O ni ki nko eru mi l'on lori

      On ni itanna ipado

      Irawo Owuro

      On nikan I’arewa ti okan mi fe.


2. Mo ko edun mi to wa

   Gbogbo banuje mi

   Gba danwo, on l’odi agbara mi, 

   Mo n‘itelorun n’nu re, 

   mo k’orisa sile

   Yio si fi agbara re dabobo mi

   Aiye le ko mi sile, esu le tan mi je 

   Nipa Jesu ngo de ‘le ileri.

Egbe: On ni ltanna ipada...


3. On ki yio fi mi sile, 

   Ko si je tan mi nu

   Ife re l’emi yio se titi dopin

   Bi mo wa l’afonifoji

   Emi ki yio beru

   Onje orun ni yio fi bo okan mi 

   Gba ba ngbade ogo, emi yio roju Re 

   Nibiti omi iye nsan titi lai.

Egbe: On ni ltanna ipada

      Irawo Owuro

      On nikan l'arewa ti okan mi fe 

      Olutunu mi l’o je

      Ninu gbogbo wahala

      O ni ki nko eru mi l'on lori

      On ni itanna ipado

      Irawo Owuro

      On nikan I’arewa ti okan mi fe. Amin

English »

Update Hymn