HYMN 645

S.S 372 (FE 671)
"Ilekun na si sile fun mi"
- Ifihan 21:251. LEKUN kan mbe t'o sipaya 

   lati inu ona re wa

   Mole lat’ ori agbelebu 

   Nf'lfe Olugbala han.

Egbe: A Anu jinle o le je

      Pe 'Iekun na si sile fun mi 

      Fun mi? - Fun mi? 

      Pe o si sile fun mi.


2. Lekun na si sile lofe

   Fun gbogbo eni nfe igbala

   F;Oloro ati talaka 

   Fun gbogbo orile-ede 

Egbe: A Anu jinle o le je...


3. Te siwaju b’ota nrojo 

   Ghati lekun na si sile 

   Gb’agbelebu jere ade 

   Anu ife ailopin.

Egbe: A Anu jinle o le je...


4. Gba ba d’oke odo lohun 

   Ao gb’agbelebu sile

   Ao bere gb’ade iye

   Ao fe Jesu si l’orun.

Egbe: A Anu jinle o le je

      Pe 'Iekun na si sile fun mi 

      Fun mi? - Fun mi? 

      Pe o si sile fun mi. Amin

English »

Update Hymn