HYMN 650

SSS 874 C.M.S 438. S 338
P.M (FE 676)
"Eje Jesu Kristi" - 1John 1:7
1. KIL’o le w’ese mi nu 

   Ko si lehin eje Jesu 

   Kil' o tun le wo mi san 

   Ko si, lehin eje Jesu.

Egbe: A! eje yebiye 

     T'o mu mi fun bi sno

     Ko si sun miran mo 

     Ko si, lehin eje Jesu.


2. Fun wenumo mi,nko ri 

   Nkan mi, lehin eje Jesu 

   Ohun ti mo gbekele 

   Fun dariji l’eje Jesu. 

Egbe: A! eje yebiye...


3. Etutu f’ese ko si 

   Ko si lehin eje Jesu 

   lse rere kan ko si 
  
   Ko si, lehin eje Jesu. 

Egbe: A! eje yebiye...


4. Gbogbo igbekele mi 

   lreti mi l'eje Jesu 

   Gbogbo ododo mi ni 

   Eje, kiki eje Jesu.

Egbe: A! eje yebiye 

     T'o mu mi fun bi sno

     Ko si sun miran mo 

     Ko si, lehin eje Jesu. Amin

English »

Update Hymn