HYMN 656

11s 10s (FE 682)
“Ife lakoja ofin" - 1Kor. 13:13
Tune: Emi l'Olorun awon ti ba nsin1. IFE pipe t’o tayo ero eda

   L’ebe l’a kunle niwaju ‘te Re 

   Jowo f’ife ti ki y’o lopin sarin 

   Awon t’lwo so sokan po lailai.


2. lye pipe jowo f‘aiya won bale 

   Nipa ife ati ‘gbagbo yiye

   Ti suru, ireti, at’ifarada

   Pelu igbekele ti ko le ye.


3. Jo fun won l’ayo ti y’o

   m‘aiye won dun

   Alafia ti y’o segun ija

   Si f’ife aiyeraiye ati Iye

   Kun okan won titi d‘ojo Ogo. Amin

English »

Update Hymn