HYMN 657

C.M.S 503 H.C 352 
T.H.C 249 7s. 6s (FE 683)
“Olorun si sure fun won” - Gen.1:281. IRE ta su ni Eden 

   N’igbeyawo kini 

   Ibukun t’a bukun won 

   O wa sibe sibe.


2. Sibe titi di oni 

   N’igbeyawo Kristian

   Olorun wa larin wa 

   Lati sure fun wa.


3. Ire ki nwon le ma bi

   Ki nwon ko si ma re

   Ki nwon ni ‘dapo mimo 

   T’enikan k’yo le tu.


4. Ba ni pe, Baba, si fa 

   Obirin yi f’oko

   Bi O ti fa Baba fun Efa 

   Adam lojo kini.


5. Ba wa pe, Immanueli 

   Si so owo won po 

   B’eda meji ti papo 

   Lara ijinle Re.


6. Ba wa pe, Emi Mirno 

   F’ibukun re fun won 

   Si se won ni asepe 

   Gege b’O ti ma se.


7. Fi nwon sabe abo Re 

   K’ibi kan ma ba won 

   Gba nwon npara ile Re 

   Ma toju okan won.


8. Pelu won l’o j’aiye won 

   At’ oko at’aiya

   Titi nwon o de odo Re 

   N’ile ayo l’orun. Amin

English »

Update Hymn