HYMN 663

ADURA TI O SAJU ONJE

C.M.S 484 H.C L.M (FE 689)
"O mu isu akara marun ati eja meji O 
gbe oju sake, O si bu u. O si fi fun
awon omo‐ehin Re” - Matt. 14:19

1. WA ba wa jeun, Oluwa

   Je ka ma yin oruko Re

   Wa busi onje wa, si je 

   Ka le ba O jeun l’orun. Amin


ADURA T’O KEHINONJE

H.C 488 L.M
“Gbogbo eda Olorun Ii o dara, bi a
ba fi ope gba a" - 1Tim 4:4

1. A F’OPE fun O, Oluwa 

   Fun onje wa at’ebun mi;

   Fi onje orun b’okan wa, 

   Onje iye lat’oke wa. Amin

English »

Update Hymn