HYMN 673

C.M.S 466 S. 17 8. 6. 8. 5 (FE 669) 
"Nwon o si je temi Ii Oluwa awon 
Omo-ogun wi, li ojo na nigbati mo 
ba nsiro oso mi" - Mal.3:171. GBAT' O ba de gbat' o ba de 

   Lati sir’oso Re

   Gbogb;'oso Re iyebiye

   Awon ti o fe.

Egbe: Bi irawo owuro, nwon

      ns’ade Re loso

      Ewa won o yo pupo 

      Ewa f’ade Re.


2. Yio ko jo, yio ko jo

   Oso ijoba Re,

   Awon mimo, awon didan 

   Awon ti ofe.

Egbe: Bi irawo...


3. Awon ewe, awon rere 

   T‘o fe Olugbala

   Ni oso Re iyebiye 

   Awon ti o fe.

Egbe: Bi irawo owuro, nwon

      ns’ade Re loso

      Ewa won o yo pupo 

      Ewa f’ade Re. Amin

English »

Update Hymn