HYMN 674

C.M.S 487 C.M (FE 700) 
ILE EKO 0J0ISIMI
"Iml mi dim nigbati nwon wifwt mi pe, Ejeka10si[la Oluwa"-PS.112:11. ILE-EKO ojo ‘simi 

   A, mo ti fe o to

   lnu mi dun mo daraya 

   Lati yo ayo re.


2. Ile-eko ojo’simi

   Ore re papoju

   T‘agba t‘ewe wa nkorin re 

   A nse aferi re.


3. lle-eko ojo' simi 

   Jesu l’o ti ko o 

   Emi Mimo Olukoni 

   L’o si nse ‘toju re.


4. lle-eko ojo’ simi 

   Awa ri eri gba 

   P‘Olorun Olodumare 

   F’ibukun sori re.


5. Ile-eko ojo simi

   B‘orun nran l’aranju

   Bi ojo su dudu lorun 

   Ninu re l’emi o wa.


6. lle‐eko ojo’ simi

   Mo ‘yo lati ri O,

   Wo y’o ha koja lori mi 

   Loni, l’airi bukun? Amin

English »

Update Hymn