HYMN 68

S.S 896 (FE 86)
“Oluwa apata mi ati Oluadande mi”
- Ps. 19:141. NGO korin ti Oludande mi

   Ati ife iyanu Re,

   O jiya lori ‘gi oro

   Lati so mi dom’nira.

Egbe: Korin ti Oludande mi,

      Eje Re l’o fi ra mi

      O f’ote re-dariji mi

      O sanwo-mo dom’nira.


2. Emi o so’tan Iyanu Re,

   B’o ti gbogun mi to ni

   Nu ‘fe at'anu ailopin

   Fi ‘dande fun mi lofe.

Egbe: Korin ti Oludande mi...


3. Ngo y’Oludande mi owon

   Ngo r’agbara segun Re

   B’o ti fun mi ni isegun

   Lor’ese at’iparun.

Egbe: Korin ti Oludande mi...


4. Ngo korin t’Oludande mi,

   T'ife at'orun wa Re,

   O mu mi la’ku si ye

   Lati ba om’Olorun gbe.

Egbe: Korin ti Oludande mi... Amin

English »

Update Hymn