HYMN 684

C.M.S 483 C.M. (FE 709)
"E yin Olorun wa, enyin iranse Re
ati ewe ati agba" - Ifi. 19:51. OLORUN orin, eniti 

   Awon Angeli nko

   Wo ‘le lati bujoko Re! 

   Ko wa k'a beru Re!


2. Oro mimo Re la fe ko 

   Lat‘ igba ewe wa

   K'a ko t’Olugbala t’ise 

   Ona, lye, Oto.


3. Jesu, ogo at‘ore Re

   L‘a nso nisiyi

   Se ‘bujoko Re s'okan wa 

   Si je k’a beru Re. Amin

English »

Update Hymn