HYMN 69

S.S. 211 (FE 87)
“A ra mi pada" - Ps. 103:41. RAPADA lowo ‘ku on ese

   lrapada n'ile l'ode

   ‘Mole titun wo lo to yi!

   Ogo wo Io tan s'okan wa.

Egbe: lrapada! I'orin mi yio je

      Titi aiye ainipekurn

      Je k’eni ‘rapada k’o ko

      Orin iyin si Kristi Oba.


2. Ogo f‘eni t'ao le mo‘fe Re

   To tan'mole s'ona enia,

   B‘itansan 'Rawo titun nyo

   A gbe rin titun rapada,

Egbe: lrapada! I'orin mi...


3. Bi ‘gbi okun ti nru soke

   Beni gb'orin ayo yio dun

   lfe Jesu jijin b'okun

   Yio k'eni 'rapada wa le.

Egbe: lrapada! I'orin mi...


4. lrapada! gbogbo eda,

   Yo f'ayo m’ore f’Oba wa

   lrapada! gbogbo aiye

   Yo d’ohun po korin iyin Re

Egbe: lrapada! I'orin mi... Amin

English »

Update Hymn