HYMN 7

P.B, C.M.S 97s 3. (FE 24)
“Oluwa, ohun mi ni iwo o 
gbo Ii owuro" - Ps. 5:3


1. JESU, Orun ododo,

   Iwo Imole ife

   Gbat' imole owuro

   Ba nt'ila orun tan wa,

   Tanmole ododo Re 

   Yi wa ka.


2. Gege bi in ti nse, 

   Son eweko gbogbo, 

   K‘Emi ore‘ofe Re

   So okan wa 'di otun; 

   Ro ojo ibuknn Re 

   Sori wa.


3. B‘imole orun ti nran 

   K‘imole ife Tire,

   Si ma ghona l‘okan wa, 

   K'o si mu wa l'ara ya, 

   K'a le ma fayo sin O, 

   L‘aiye wa.


4. Amona, lreti wa, 

   Ma fi wa sile tili, 

   Fi wa sabe iso Re, 

   Titi opin emi wa, 

   Sin wa la ajo wa ja 

   S‘ile wa.


5. Pa wa mo n'nu ife Re, 

   Lojo aiye wa gbogbo,

   Si mu wa bori iku,

   Mu wa de'le ayo na, 

   K'a le b‘awon mimo 

   gba isin mi. Amin

English »

Update Hymn