HYMN 725

P.M1. AWA f’ori bale fun/O Jesu

   Wo ti s’Olori ljo awon/eniyan Re 

   Ijo ti mbe laye yi ati lo/run pelu 

   Ale/luya.


2. Wo t‘oku, t‘o si jin/de fun wa

   T’o mbe lodo Baba bi Ala/gbawi wa 

   K‘ogo atolanlan/je Tire

   Ale/luya.


3. Ati li ojo nla Pen/tikosi

   Ti o ran Paraklitj/si aye 

   Olutunu nla Re ti/mba wa gbe 

   Ale/luya.


4. Lat’ori ite Re l’ok/ke orun

   L'o o si nwo gbogbo awon o/jise Re 

   T'o si nsike gbogbo awon Aje/riku Re 

   Ale/luya.


5. A fi iyin at'olanlan f’o/ruko Re 

   N'tori iku gbogbo awon o/jise Re

   Ni gbogbo ile, Yo/ruba yi 

   Ale/luya. Amin

English »

Update Hymn