HYMN 726

77751. OLORUN Metalokan

   Oba ile at’okun 

   Gbo ti wa bi a nko 

   Orin iyin Re.


2. Wo imole l‘owuro

   Tan ‘mole Re yi wa ka 

   Jeki ebun rere Re 

   M'aya wa bale.


3. Wo ‘mole nigb‘orun wo 

   K'a ri idariji gba

   Ki alafia orun

   F'itura fun wa.


4. Olorun Metalokan

   lsin wa l’aye ko to

   A nreti lati dapo

   Mo awon t'orun. Amin

English »

Update Hymn