HYMN 736

C.M.S 115 t.H.C 559 6s 8s (FE 762)
"Yio si joba ni Jakobu titi aiye” - Luk.1:33 
Tune: Gba Ti Samueli Ji1. E YO, Jesu joba 

   ‘Nu omo enia

   O da ara tubu

   O so won d‘ominira 

   K’esu koju s‘om’ Olorun 

   Lai f'ota pe ise Re nlo.


2. lse ti ododo 

   Oto, alafia

   Fun r’orun aiye wa

   Yio tan ka kiri 

   Keferi, Ju nwon o wole 

   Nwon o jeje isin yiye.


3. Agbara l’owo Re 

  Fun abo eni Re

  Si ase giga Re

  L’opo o kiyesi 

  Orun ayo ri ise Re, 

  Ekusu rere gb’ofin Re.


4. Serafu (Kerubu) t’ aiye yi 

   O fere d’ijo nla

   Abukun wukara 

   Ko le sai tan kiri

   Tit’ Olorun Omo tun wa 

   Ko le sai lo. Amin! Amin! Amin

English »

Update Hymn