HYMN 751

H.C 510 t.H.C App 12P.M (FE 785) 
“Odo omi lye Mimo” - Ifi. 22:11. A o pade leti odo, 

   T’ese Angeli ti te

   T‘o mo gara bi Kristali 

   Leba ite Olorun.

Egbe: A o pade leti odo,

     Odo didan, Odo didan na, 

     Pelu awon Mimo Ieba odo, 

     To san Ieba ite ni.


2. Leti bebe odo na yi 

   Pel’ Oluso-agutan wa, 

   A o ma rin ao ma sin, 

   B’a ti ntele ‘pase Re.

Egbe: A o pade leti odo...


3. K'a to de odo didan na, 

   A o s‘eru wa kale

   Jesu, y'o gba eru ese 

   Awon ti o de l'ade.

Egbe: A o pade leti odo...


4. Nje leba odo tutu na,

   A o r'oju Olugbala 

   Emi wa ki o pinyan mo, 

   Yio korin Ogo Re.

Egbe: A o pade leti odo,

     Odo didan, Odo didan na, 

     Pelu awon Mimo Ieba odo, 

     To nsan Ieba ite ni. Amin

English »

Update Hymn