HYMN 753

H.C 574 7s (FE 787)
“On o wo inu Alafia” - Isa.57:21. AWON t’o sowon fun wa 

   Ninu Egbe Serafu

   Nwon ti lo s’aiyeraiye 

   Ko ha ye k‘a ranti won?


2. Awon t'o sowon fun wa 

   Larin Egbe Kerubu 

   Nwon dapo mo jo t'orun 

   lse won nto won lehin.


3. Awon t’o sowon fun wa 

   Ninu Egbe Aladura

   Enit’ o ku ti pari 

   Ise re l’odo Jesu.


4. Awon wonyi ti segun 

   F’Ola Olugbala won 

   Nwon ti gb’ohun Jesu pe 

   Bo s’ayo Oluwa Re.


5. Oluwa gbadura wa 

   K’a le ni ‘po lodo Re 

   K‘a ma tan bi irawo 

   Titi lai lod’Oluwa.


6. E f’ogo fun Baba wa, 

   E f’ogo fun Omo Re

   E f’ogo Emi Mimo

   Ogo fun metalokan. Amin

English »

Update Hymn