HYMN 755

C.H. 372 t.H.C 140 C.M (FE 789)
“Alabukun fun li awon oku ti o ku
nipa ti Oluwa” - Ifi.14:131. GB'ohun t’o t‘orun wa ti wi 

   F’awon oku mimo

   Didun n‘irant’oruko won 

   Busun won n’itura.


2. Nwon ki n’nu Jesu abukun 

   Orun won ti dun to!

   Ninu irora on ese

   Nwon yo ninu danwo.


3. Lona jijin s’ayie ise 

   Nwon mbe lod’Oluwa 

   Ise won l‘aiye iku yi 

   Pari li ere nla. Amin

English »

Update Hymn