HYMN 756

C.M.S 514 7s (FE 790) 
“Jesu, Iwo omo Dafidi, sanu fun wa"
 - Mar. 10:471. GBA ta kun fun ‘banuje 

   Gb’omije nsan loju wa 

   Gbat’o nsokun t’a nsofo 

   Olugbala, gbo tiwa.


2. Wo ti gbe ara wa wo 

   O si mo ‘banuje wa

   O ti sokun bi awa 

   Olugbala, gbo tiwa.


3. Wo ti teriba fun ku 

   Wo ti t’eje Re sile 

   A te O si posi ri 

  Olugbala, gbo tiwa.


4. Gbat’ okan wa ba baje 

   Nitori ese t’a da

   Gbat’ eru ba b’okan wa 

   Olugbala, gbo tiwa.


5. Wo ti mo eru ese, 

   Ese ti ki se Tire 

   Eru ese na l'O gbe 

   Olugbala, gbo tiwa.


6. O ti silekun iku

  O ti s’etutu f’ese

  O wa l’ow otun Baba 

  Olugbala, gbo tiwa. Amin

English »

Update Hymn