HYMN 757

H.C 2nd Ed 443 7s 3s (FE 791)
“Goke Jordani" - Jos 3:171. A! nwon ti gun s’ebute 

   Loke orun, Loke orun

   Ebi ko ni pa won mo 

   Nown bo lowo irora 

   Loke orun, Loke orun.


2. A! nwon ko wa fitila 

   Loke orun: loke orun 

   Mole ni I‘ojo gbogbo 

   Jesu si n’lmole won 

   Loke orun: loke orun.


3. A! wura n’ita won je 

   Loke orun: loke orun 

   Ogo ‘be si po pupo 

   Agbo Jesu ni nwon je 

   Loke orun: loke orun.


4. A! otutu ki mu won 

   Loke orun: loke orun

   Owore won ti koja 

   Gbogbo ojo l’o dara 

   Loke orun: loke orun.


5. A! nwon dekun ija ja 

   Loke orun: loke orun 

   Jesu l’o ti gba won la 

   T’awon Tire l’o si nrin 

   Loke orun: loke orun.


6. A! nwon ko ni sokun mo 

   Loke orun: loke orun 

   Jesu sa wa lodo won 

   Lodo Re ni ayo wa

   Loke orun: loke orun.


7. A! a o dapo mo won

   Loke orun: Ioke orun

   A nreti akoko wa

  Gba Oluwa ba pe ni

  S’Oke orun, S’oke orun. Amin

English »

Update Hymn