HYMN 766

S.S. 966. (FE 800)
“Ao duo niwaju Oba" - Jere. 15:91. Ao duro niwaj’ Oba

   Ao b’awon Angeli korin 
 
   Nigbose, nigbose,

   Ao ma yan l’ebute na, 

   Ao si ma yin titi lai 

  Nigbose, nigbose.

Egbe: Ao duro niwaj’Oba

     Ao b’awon Angel’korin 

     Ogo, Ogo, s’Oba wa, 

     Halleluya, Halleluya, 

     Ao duro niwaj'Oba.


2. Agogo orun! e lu

   Ao duro niwaj’ Oba 

   Nigbose, Nigbose, 

   Banuje y’o tan nibe

   Ao si mayo l’Oko Re... 

   Nigbose, Nigbose.

Egbe: Ao duro niwaj’Oba...


3. Nde! okan m’ore wa, 

   ‘Wo o duro niwaj’ Oba 

   Nigbose, Nigbose,

   ‘Da’ kogun re s’ese Re, 

   Si gba pipe ewa Re 

   Nigbose, Nigbose.

Egbe: Ao duro niwaj’Oba

     Ao b’awon Angel’korin 

     Ogo, Ogo, s’Oba wa, 

     Halleluya, Halleluya, 

     Ao duro niwaj'Oba. Amin

English »

Update Hymn