HYMN 768

(FE 802)
"Wa pelu mi ni Paradise" - Luku 23:43
Tune: Jesu mo wa sodo re1. OJO Wura oj’Olorun 

   T’okan aise nin’ogbe na

   Nib’ayo nla ko si l’aiye 

   Bi tura ni Paradise.

Egbe: Paradise...Paradise

     A pe k'a to f’aiye sile 

     Nib’imole...Paradise 

     Jesu j‘Oba loke lohun.


2. Subu ara, ese‘tiju

   Iku ‘dajo, Ida 'jo won 

   Dekun ese pare lohun 

   Aiye lo ni Paradise.

Egbe: Paradise...


3. Ko s’adura, ko si ewu 

   Ko s’edun mo, ipo sofo 

   Boji ati ibanuje

   Ko si won ni Paradise.

Egbe: Paradise...


4. Krist’Oluwa lori igi 

   Elese ke, pe ranti mi 

   Loni ‘wo y’o Oluwa wi 

   Pelu mi ni Pradaise.

Egbe: Paradise...


5. Ojo wura, gba Krsiti ji 

   Boji sile, aro si pin 

   Ogo nla bo, oku ji, y’o 

   Ba joba ni Paradise.

Egbe: Paradise...


6. Kerubu ho, Serafu yo 

   Eyi ko ha t’ayo re bi 

   Pe Jesu la ona ‘gbala 

   Lati aiye lo de orun.

Egbe: Paradise...


7. Tera-mose, ni ere re 

   Lati le ri ‘hin rere je

   K’a ma kuna Paradise 

   Ope ni fun Metalokan.

Egbe: Paradise...Paradise

     A pe k'a to f’aiye sile 

     Nib’imole...Paradise 

     Jesu j‘Oba loke lohun. Amin

English »

Update Hymn