HYMN 771

C.M.S 526 7s (FE 805)
“Ororo ile re yi te won lorun 
gidigidi” - Ps.36:81. ISIN Jesu ni funni 

   L’ayo toto, laiye yi

   Isin Jesu ni funni

   N’itunu ninu iku.


2. Lehin ‘ku ayo na mbe 

   Ti ko ni d’opin lailai 

   K’Olorun sa je temi

   Ayo mi ki o l’opin. Amin

English »

Update Hymn