HYMN 775

C.M.S 10 H.C 15 6s (FE 809) 
“Olorun ni kutukutu l'emi o ma
s'aferi Re" - Ps. 63:11. BABA mi gbo temi 

   Wo ni Alabo mi 

   Ma sunmo ni titi 

   Oninure julo!


2. Jesu Oluwa mi

   Iye at’ogo mi 

   K’igba na yara de 

   Ti ngo de odo Re.


3. Olutunu julo

   Wo ti ngbe inu mi 

   Wo to mo aini mi 

   Fa mi, ko si gba mi.


4. Mimo, Mimo, Mimo 

   Ma fi mi sile lai 

   Se mi n’ibugbe Re 

   Tire nikan lailia. Amin

English »

Update Hymn