HYMN 776

C.M.S 594 S.272 P.M (FE 810) 
"E ma wa inu lwo Mimo, nitori ninu 
won I‘enyin ni lye ainipekun"- John. 5:391. E TUN won ko fun mi ki ngbo, 

   Oro ‘yanu t’Iye

   Je ki nsi tun ewa won ri

   Oro ‘yanu t’lye

   Oro lye at‘ewa ti nko mi n’igbagbo 

   Oro didun! Oro ‘yanu

   Oro ‘yanu t’lye.


2. Kristi nikan l’o nfi funni 

   Oro ‘yanu at’lye

   Elese gbo ‘pe ife na

   Oro ‘yanu at’Iye

   L’ofe l‘a fifun wa, ko le to wa sorun! 

   Oro didun! Oro ‘yanu

   Oro ‘yanu t’lye.


3. Gbe ohun ihinrere na 

   Oro ‘yanu at’lye 

   F’lgbala lo gbogbo enia 

   Oro ‘yanu at’lye

   Jesu Olugbala, we wa mo titi lai! 

   Oro didun! Oro ‘yanu!

   Oro ‘yanu at’lye. Amin

English »

Update Hymn