HYMN 778

C.M.S 549 8s.7s (FE 812)
"Ore-Ofe Jesu Kristi Oluwa wa, ati lfe
Olorun idapo ti Emi Mimo, ki o ma ba 
gbogbo wa gbe titi lai" - 2Kor. 13:141. K‘ORE-OFE Krist’Oluwa 

   Ife Baba ailopin

   Oju rere Emi Mimo 

   K'o t’oke ba s’ori wa.


2. Bayi l’a le wa n’irepo 

   Ninu wa pel’Oluwa, 

   K’a si le n’idapo didun 

   At’ayo t'aiye ko ni. Amin

English »

Update Hymn