HYMN 791

(FE 825) 8s 4s 
"Wakati Adura” - Ise 3:1
Tune: “Oluwa orun on aye”1. OLORUN lat‘oro d'ale 

   Wakati wo lo dun pupo 

   B'eyi to pe mi wa do Re 

   Fun Adura? - 2ce


2. lbukun n’itura oro 

   lbukun si l'oju ale 

   Gbati mo f’adura goke 

   Kuro l’aiye.


3. Gbana mole kan mo si mi 

   O dan ju mole orun lo

   Iri bukun t'aiye ko mo 

   T'odo Re wa.


4. Gbana l'agbara mi d’otun 

   Gbana l'a f’ese ji mi 

   Gbana l'o f'ireti orun 

   M‘ara mi ya.


5. Enu ko Ie so ibukun

   Ti mo nri f'aini mi gbogbo 

   Agbara, itunu, ati Alafla.


6. Eru ati iyemeji tan 

   Okan mi f’orun se ile 

   Omije ‘ronupiwada 

   L’a nu kuro.


7. Titi ngo de ‘le bukun na 

   Ko s'anfani t’o le dun, bi 

   Ki nma tu okan mi fun O 

   Nin'adura. Amin

English »

Update Hymn