HYMN 799

(FE 834)
“Olubukun ni Oluwa titi lailai”
 - Ps.89:521. Oba rere wa wa gbo - 2ce 

   F’ire fun wa loni Baba o 

   Ye dakun, Baba rere.

Egbe: Ire-Ire o, Baba - 2ce

      Ire owo ni-Ire o, Baba

      Ire omo ni-Ire o, Baba, 

      K’a agbadura ire ti mbe n’isale 

      Eyiti mbo loke, ma fi wa sehin; 

      Baba rere.


2. A juba Ajodun - 2ce 

   K’ajodun yi san wa loni o 

   K‘a r’ire kari kari

Egbe: Ire-Ire o, Baba...


3. K’a gbadun ajodun 2ce 

   K’ajodun yi an wa loni o 

   K’a r’ire kari kari. 

Egbe: Ire-Ire o, Baba...


4. Olu Orun ye - 2ce

   Ki a to pada sile wa o 

   K’a r’ire Baba rere.

Egbe: Ire-Ire o, Baba...


5. Olubukun ni O - 2ce 
  
   Bukun fun wa loni Baba o, 

   Ye dakun, Eni rere.

Egbe: Ire-Ire o, Baba...


6. Olupese ni o - 2ce 

   Pese fun wa loni Baba o 

   Ye dakun, Baba rere.

Egbe: Ire-Ire o, Baba - 2ce

      Ire owo ni-Ire o, Baba

      Ire omo ni-Ire o, Baba, 

      K’a agbadura ire ti mbe n’isale 

      Eyiti mbo loke, ma fi wa sehin; 

      Baba rere. Amin

English »

Update Hymn