HYMN 8

C.M.S 596, t.H.C. 552, L.M. (FE 25)
"Orun ododo yio la fun enyin t'o 
beru oruko mi" - Mal 4:2.


1. ORUN Ododo, jowo la,

   Ma ran jeje lori Sioni 

   Tu okunkun oju wa ka 

   Je k'okan wa ko ji si ye.


2. Jek'ore ofe ba le wa, 

   B‘iri orun, b’opo ojo;

   K'a le mo p'On l‘Ore wa san, 

   Ka le pe 'gbala ni tiwa. Amin

English »

Update Hymn