HYMN 807

(FE 842)
“Orin isedale Egbe Kerubu ati Serafu
Mimo, ti a da sile lati owo Alagba wa, 
Moses Orimolade”1. LOKE odo Jordani 

   L’a pe mi - 2ce

   Awon olufe mi to ti lo, to ti lo 

   Mo fe lo ba won wole ogo

   A ki yo ya mo titi lailai lailai 

  Wo sile, wo sile ife

  Iwe Jesu so fun mi pe

  Angeli gbe mi lo mo ayo, 

  Jesu si mu mi wole. Amin

English »

Update Hymn