HYMN 819
(FE 855)
1.  OLUGBALA, Olugbala ni Baba 
Olugbala, Olugbala, ni Omo
Olugbala, ni Emi Mimo 
Olugbala, ni Metalokan.
2.  Alabo, Alabo, ni Baba 
Alabo, Alabo ni Omo, 
Alabo, ni Emi Mimo 
Alabo, ni Metalokan.
3.  Olupese, Olupese, ni Baba 
Olupese, Olupese ni Omo 
Olupese, ni Emi Mimo 
Olupese, ni Metalokan.
4.  Oluwosan, Oluwosan, ni Baba 
Oluwosan, Oluwosan ni Omo, 
Oluwosan, ni Emi Mimo 
Oluwosan, ni Metalokan.
5.  Oluwoye, Oluwoye, ni Baba 
Oluwoye, Oluwoye ni Omo, 
Oluwoye, ni Emi Mimo 
Oluwoye, ni Metalokan.
6.  Olusegun, Olusegun, ni Baba 
Olusegun, Olusegun ni Omo,
Olusegun, ni Emi Mimo 
Olusegun, ni Metalokan.
7.  Olulana, Olulana, ni Baba 
Olulana, Olulana ni Omo, 
Olulana, ni Emi Mimo 
Olulana, ni Metalokan.
8.  E patewo, E patewo, fun Baba
E patewo, E patewo fun Omo,
E patewo, fun Emi Mimo 
E patewo, fun Metalokan.
9.  E fo soke, e fo soke fun Baba
E fo soke, e fo soke fun Omo,
E fo soke, fun Emi Mimo 
E fo soke, fun Metalokan.
10.  E dobale, E dobale, fun Baba 
E dobale, E dobale fun Omo,
E dobale, Emi Mimo 
E dobale, fun Metalokan.  Amin
BY DR. H. O. ATANSUYI 2003
English »Update Hymn