HYMN 825

S.S & S 745 (FE 862)
“Iwo ma beru, nitori mo wa pelu re"
 - lsa. 41:101. NIGABTI ‘gbi aiye yi ba mbu lu o

   T‘okan re nporuru t'o ro pe o gbe

   Siro ibukun re, ka won l’okokan,

   Enu yio si ya o f’ohun t’Oluwa se.

Egbe: Siro ibukun re, ka won l’okokan,

      Siro ibukun re, w'ohun 

      t'OIuwa se

      Siro ibukun re, ka won l'okokan

      Enu yio si ya o f’ohun

      t‘Oluwa se.


2. Aniyan ha sesi kun okan re ri?

   Agbelebu re ha wuwo rinrin bi? 

   Siro ibukun re, le 'yemeji lo,

   Okan re yio si kun f'orin iyin.

Egbe: Siro ibukun re...


3. B'o ti nwo elomi to se gbede fun, 

   Ronu wipe Jesu ko ni gba gbe re: 

   Siro ibukun re t‘oko fowo ra, 

   Ere ti o duro de o l'oke orun.

Egbe: Siro ibukun re...4. Nje ninu idamu re li aiye yi

   Ma so ‘reti nu, Oluwa wa, fun o 

   Siro ibukun re, f’awon Angeli re

   Yio duro ti o titi de opin.

Egbe: Siro ibukun re, ka won l’okokan,

      Siro ibukun re, w'ohun 

      t'OIuwa se

      Siro ibukun re, ka won l'okokan

      Enu yio si ya o f’ohun

      t‘Oluwa se. Amin

English »

Update Hymn