HYMN 826

(FE 863)
"Silekun fun wa" - Matt. 25:111. SILEKUN fun wa o - 2ce 

   Iwe lo ni wa

   Mase ta wa nu

   Silekun fun wa o.


2. Wa pese fun wa o - 2ce 

   lwo lo ni wa 

   Jehofa-Jireh

   Wa pese fun wa o.


3. Wa f‘oyin s‘aiye wa - 2ce 

   Iwo l'o l‘aiye 

   Jehova-Nissi

   Wa f'oyin s'aiye wa.


4. Ma jek’ a sonwo lo - 2ce

   Bukun fun wa se

   Jehova‐Barak

   Ma je k’a sonwo lo

   Amin o! Ase, beni k’o ri o. Amin

English »

Update Hymn