HYMN 828

(FE 865)
"O si wi fun won pe, E ma to mi
Iehin” - Matt.4:191. ONIGBAGBO, e wa

   Isreali t'emi

   Jesu mbebe pupopupo 

  Bi Alagbawi wa.

Egbe: E ho, e yo, f'inu didun gberin 

     Enyin 'Male ati Keferi

     E wa si 'mole.


2. Nigbat' ojo 'dajo ba de 

   Bawo ni wo o ti wi 

   Gbat‘ o pin fun kaluku 

   Gege bi ise re.

Egbe: E ho, e yo...


3. Nigbati nwasu nijosi 

   Iwo ko si nibe

   Mase tun wi awawi mo

   Bo sinu imole.

Egbe: E ho, e yo...


4. E f‘Ogo fun Baba loke 

   E f‘Ogo fun Omo

   E f’Ogo fun Emi Mimo

   Metalokan lailai.

Egbe: E ho, e yo, f'inu didun gberin 

     Enyin 'Male ati Keferi

     E wa si 'mole. Amin

English »

Update Hymn