HYMN 833

C.M (FE 870)
Awo ati, ija ohun ti ko dara ni1. A JA ni gbo-Ekun aja 

   Be l‘a sa s‘ede won 

   Ogidan, l'ola iju 

   L‘akomo l'ain obe.


2. Sugbon enia l’a da nyin 

   E hu wa bi omo

   K‘e mase ba ara nyin ja 

   Ere ni k’e ma se.


3. Bi Omo-rere Maria 

   Ni k’iwa nyin tutu 

   K’e po n’ife bi Oluwa 

   Jesu Om'Olorun.


4. Eni jeje bi agutan

   Ti iwa Re wun ni 

   Enia ati Olorun 

   N’idagba Re si won.


5. Oluwa gunwa bi Ona 

   L'ori ‘te Re lorun

   O nwo aw' omo t‘o n'ife 

   O si nsami si won. Amin

English »

Update Hymn