HYMN 838

C.M.S 463, H.C 368 6s 5s (FE 875) 
“Enyin o mo otito, Otito yio si so 
nyin di ominira” - John 8:321. JESU Onirele, 

   Omo Olorun 

   Alanu, Olufe, 

   Gbo ‘gbe omo Re.


2. Fi ese wa ji wa, 

   Si da wa n’ide, 

   Fo gbogbo orisa, 

   Ti mbe l’okan.


3. Fun wa ni omnira, 

   F’ife s’okan wa’ 

   Fa wa, Jesu mimo 

   S’ibugbe l’oke.


4. To wa l’ona ajo, 

   Si je ona wa,

   La okun aiye ja, 

   S’imole orun.


5. Jesu Onilere,

   Omo Olorun;

   Alanu, Olufe

  Gbo ‘gbe omo Re. Amin

English »

Update Hymn