HYMN 840

(FE 877)
"Ife Kristi li o nro wa" - 2Kor5:14
Tune: S.S & S 381. O DUN mo mi pe Baba wa orun 

   So nipa ife n'nu lwe lye

   lyanu ni eko ti Bibeli

   Nko mi wipe, Jesu lo feran mi.

Egbe: O dun mo mi, Jesu feram mi 

     O feran mi, O feran mi

     O dun mo mi, Jesu feran mi 

     Jesu lo feran mi.

2. Bi mo gbagbo ti mo si sako lo 

   Sibe o feran mi n’nu ‘sako mi

   Mo si wa sabe apa ife re

   Gba mo ranti pe Jesu feran mi.

Egbe: O dun mo mi...


3. Orin kan wa ti emi yio ko 

   N’nu Ewa Oba Ogo l'ao ri 

   Eyi ni orin ti emi y'o ko 

   Iyanu nla ni” Jesu feran mi.

Egbe: O dun mo mi...


4. Jesu feran mi, mo mo daju pe 

   lfe lo fira okan mi pada

   Ti O fi ku fun mi lori Igi

   A! o daju pe, Jesu feran mi.

Egbe: O dun mo mi...


5. B'a bi mi, Bawo ni mo se le so? 

   Ogo fun Jesu, emi mo daju

   Emi Olorun tun nso ninu mi

   O nso, O nso pe, Jesu feran mi.

Egbe: O dun mo mi...


6. N‘nu idaju yi ni mo n‘isimi

   N’nu ‘gbekele yi mo r’ibukun gba 

   Satani kuro ninu okan mi

   Mo mo daju pe, Jesu feran mi.

Egbe: O dun mo mi, Jesu feram mi 

     O feran mi, O feran mi

     O dun mo mi, Jesu feran mi 

     Jesu lo feran mi. Amin

English »

Update Hymn