HYMN 841

(FE 878)
"Nitoriti iwo o je ise owo re" - Ps.128:2
Ohun ti o ba gbin ni iwo yio ka1. OM’ Egbe Kerubu Serafu 

   Sora iru ohun to nghin

   Yala alikama tab‘ epo 

   Ohun to ba gbin n'iwo o ka.

Egbe: Ohun to ba gbin n’iwo o ka - 2ce 

      Akoko ikore tete

     Ohun to ba gbin n‘iwo o ka.


2. Gbin ‘bukun, ibukun y’o si pon 

   Gbin irora, y‘o si dagba

   Gbin anu, wo o si gbadun re, 

   Ohun to ba gbin n‘iwo o sa.

Egbe: Ohun to ba gbin...


3. Gbin ife, ife yio si tan

   Si inu gbogbo okan re

   Gbin ireti, si ka eso re 

   Ohun to ba gbin n’iwo o ka.

Egbe: Ohun to ba gbin...


4. N'igbagbo, gbin oro Oluwa 

   Wo o si ri ‘bukun re gba 

   Opo irawo n'nu ade re 

   Ohun to ba gbin n’iwo o ka.

Egbe: Ohun to ba gbin...


5. Wasu Kristi pelu ‘kanu Re 

   K'aiye le mo igbala Re

   Wo yio ka iye ainipekun 

   Ohun to ba gbin n'iwo o ka.

Egbe: Ohun to ba gbin n’iwo o ka - 2ce 

      Akoko ikore tete

     Ohun to ba gbin n‘iwo o ka. Amin

English »

Update Hymn