HYMN 842

C.M.S 459 H.C 469 6s 5s (FE 879)
"Nigbati iwo dubule, iwo ki yio beru"
- Owe 3:241. OJO oni lo tan
 
   Oru sunmole

   Okunkun si de tan 

   Ile si ti su.


2. Okunkun bo ile 

   Awon ‘rawo yo 

   Eranko at'eiye

   Lo si ‘busun won.


3. Jesu, f’orun didun 

   F’eni alare

   Jeki ibukun Re 

   Pa oju mi de.


4. Jek’ omo kekekre

   La ala rere

   S’oloko t‘ewu nwu 

   Ni oju omi.


5. Ma toju alaisan 

   Ti ko r’orun sun 

   Awon ti nro ibi 

   Jo da won l’ekun.


6. Ninu gbogbo oru 

   Jek’ Angeli Re 

   Mase oluso mi 

   L’ori eni mi.


7. Gbat' ile na si mo 

   Jek'emi dide 

   B'omo ti ko l’ese 

   Ni iwaju Re.


8. Ogo ni fun Baba 

   Ati fun Omo

   Ati f’Emi Mimo 

   Lai ati Iailai. Amin

English »

Update Hymn