HYMN 85

1. O DA mi loju, Jesu n’ temi

   Itowo adun orun l’eyi je

   Mo di ajogun igbala nla

   Eje Re we mi, a tun mi bi.

Egbe: Eyi ni ‘tan mi at ‘orin mi

      Ngo yin Olugbala mi titi

      Eyi ni ‘tan mi at’ orin mi

      Ngo yin Olugbala mi titi.


2. ‘Teriba pipe, ayo pipe

   Mo n ri iran ogo bibo Re

   Angeli n mu ihin didun wa

   Ti ife at’aanu Re si mi

Egbe: Eyi ni ‘tan mi...


3. “Teriba pipe, isin mi ni

   Ninu Kristi mo d’eni ‘bukun

   N’igba gbogbo mo n w'oke orun

   Mo si kun f‘oore at’ife Re.

Egbe: Eyi ni ‘tan mi... Amin

English »

Update Hymn